Jẹ́nẹ́sísì 38:17 BMY

17 Ó sì wí pé, “Èmi yóò fi ọmọ ewúrẹ́ kan ránṣẹ sí ọ láti inú agbo ẹran.”Obìnrin náà sì dáhùn pé, “Ṣé ìwọ yóò fún mi ní ohun kan gẹ́gẹ́ bí ẹ̀rí títí tí ìwọ yóò fi fi ránṣẹ́?”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 38

Wo Jẹ́nẹ́sísì 38:17 ni o tọ