Jẹ́nẹ́sísì 38:23 BMY

23 Nígbà náà ni Júdà wí pé, “Jẹ́ kí ó máa kó àwọn ohun tí ó wà lọ́wọ́ rẹ̀ lọ bí kò ṣe bẹ́ẹ̀ a ó di ẹlẹ́yà. Mo sáà fi ọmọ ewúrẹ́ ránṣẹ́ sí i, ṣùgbọ́n ìwọ kò rí òun.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 38

Wo Jẹ́nẹ́sísì 38:23 ni o tọ