Jẹ́nẹ́sísì 38:28 BMY

28 Bí ó sì ti ń bímọ, ọ̀kan nínú àwọn ọmọ náà na ọwọ́ jáde; agbẹ̀bí sì so okùn òdòdó mọ́ ọmọ náà ní ọrùn ọwọ́. Ó sì wí pé, “Èyí ni o kọ́kọ́ jáde.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 38

Wo Jẹ́nẹ́sísì 38:28 ni o tọ