Jẹ́nẹ́sísì 38:8 BMY

8 Nígbà náà ni Júdà wí fún Ónánì, “Bá aya arákùnrin rẹ lò pọ̀, kí o ṣe ojúṣe rẹ fun un gẹ́gẹ́ bí àbúrò ọkọ, kí ó ba à le bí ọmọ fún un ní orúkọ arákùnrin-ìn rẹ.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 38

Wo Jẹ́nẹ́sísì 38:8 ni o tọ