Jẹ́nẹ́sísì 39:1 BMY

1 Nígbà tí wọ́n mú Jósẹ́fù dé Éjíbítì, Pótífà, ará Éjíbítì tí i ṣe ọ̀kan nínú àwọn ìjòyè Fáráò. Òun ni olórí àwọn ọmọ ogun Fáráò. Ó ra Jósẹ́fù lọ́wọ́ àwọn ará Íṣímáẹ́lì tí wọ́n mú-un lọ ṣíbẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 39

Wo Jẹ́nẹ́sísì 39:1 ni o tọ