Jẹ́nẹ́sísì 39:19 BMY

19 Nígbà tí Pọ́tífà gbọ́ ọ̀rọ̀ aya rẹ̀ pé báyìí ni ẹrú rẹ̀ ṣe sí aya rẹ̀, ó bínú gidigidi.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 39

Wo Jẹ́nẹ́sísì 39:19 ni o tọ