Jẹ́nẹ́sísì 39:5 BMY

5 Láti ìgbà tí ó ti fi Jósẹ́fù jẹ olórí ilé rẹ̀ àti ohun-ìní rẹ̀ gbogbo, ni Ọlọ́run ti bẹ̀rẹ̀ sí ní bùkún-un nítorí Jósẹ́fù. Ìbùkún Olúwa wà lórí gbogbo ohun tí Pọ́tífà ní, nílé àti lóko.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 39

Wo Jẹ́nẹ́sísì 39:5 ni o tọ