Jẹ́nẹ́sísì 4:17 BMY

17 Káínì sì bá aya rẹ̀ lò pọ̀, ó sì lóyún, ó sì bí Énókù. Káínì sì tẹ ìlú kan dó, ó sì fi orúkọ̀ ọmọ rẹ̀ ọkùnrin Énókù sọ ìlú náà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 4

Wo Jẹ́nẹ́sísì 4:17 ni o tọ