Jẹ́nẹ́sísì 4:23 BMY

23 Lámékì wí fún àwọn aya rẹ̀,“Ádà àti Ṣílà, ẹ tẹ́tí sí mi;ẹ̀yin aya Lámékì, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ mi.Mo ti pa ọkùnrin kan tí ó kọlù mí,ọ̀dọ́mọkùnrin tí ó pa mí lára.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 4

Wo Jẹ́nẹ́sísì 4:23 ni o tọ