Jẹ́nẹ́sísì 4:25 BMY

25 Ádámù sì tún bá aya rẹ̀ lò pọ̀, ó sì bí ọmọkùnrin kan tí ó pe orúkọ rẹ̀ ní Ṣẹ́tì, tí ó túmọ̀ sí pé, “Ọlọ́run fún mi ní ọmọkùnrin mìíràn ní ipò Ábélì tí Káínì pa.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 4

Wo Jẹ́nẹ́sísì 4:25 ni o tọ