Jẹ́nẹ́sísì 4:9 BMY

9 Nígbà náà ni Olúwa béèrè lọ́wọ́ Káínì pé, “Níbo ni Ábélì arákùnrin rẹ wà?”Ó sì dáhùn pé, “Èmi kò mọ ibi tí ó wà, èmí ha ń ṣe olùṣọ́ arákùnrin mi bí?”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 4

Wo Jẹ́nẹ́sísì 4:9 ni o tọ