Jẹ́nẹ́sísì 40:1 BMY

1 Kò pẹ́ lẹ́yìn èyí, ni agbọ́tí ọba àti alásè rẹ̀ ṣẹ ọba Éjíbítì, olúwa wọn.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 40

Wo Jẹ́nẹ́sísì 40:1 ni o tọ