Jẹ́nẹ́sísì 40:12 BMY

12 Jósẹ́fù wí fún-un pé, “Èyí ni ìtumọ̀ àlá rẹ. Ẹ̀ka mẹ́ta náà dúró fún ọjọ́ mẹ́ta.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 40

Wo Jẹ́nẹ́sísì 40:12 ni o tọ