Jẹ́nẹ́sísì 40:20 BMY

20 Ọjọ́ kẹ́ta sì jẹ́ ọjọ́ ìbí Fáráò, ó sì ṣe àsè fún gbogbo àwọn ìjòyè e rẹ̀. Ó sì mú olórí agbọ́tí àti olórí aláṣè jáde kúrò nínú ẹ̀wọ̀n.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 40

Wo Jẹ́nẹ́sísì 40:20 ni o tọ