Jẹ́nẹ́sísì 41:15 BMY

15 Fáráò wí fún Jósẹ́fù, “Mo lá àlá kan, kò sì sí ẹni tí o le è túmọ̀ rẹ̀. Ṣùgbọ́n mo ti gbọ́ nípa rẹ pé bí o bá ti gbọ́ àlá, o le è túmọ̀ rẹ̀”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 41

Wo Jẹ́nẹ́sísì 41:15 ni o tọ