Jẹ́nẹ́sísì 41:25 BMY

25 Nígbà náà ni Jósẹ́fù wí fún Fáráò, “Ìtúmọ̀ kan náà ni àwọn àlá méjèèjì ní. Ọlọ́run fi ohun tí ó fẹ́ ṣe hàn fún Fáráò.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 41

Wo Jẹ́nẹ́sísì 41:25 ni o tọ