Jẹ́nẹ́sísì 41:27 BMY

27 Àwọn màlúù méje tí kò sanra, tí kò sì rẹwà tí ó jáde gbẹ̀yìn jẹ́ ọdún méje, bẹ́ẹ̀ náà ni siiri ọkà méje tí kò dára, tí afẹ́fẹ́ ìlà oòrun ti rẹ̀ dànù tan: Wọn jẹ́ ọdún méje tí ìyàn yóò fi mú.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 41

Wo Jẹ́nẹ́sísì 41:27 ni o tọ