Jẹ́nẹ́sísì 42:30 BMY

30 “Ọkùnrin náà tí í ṣe alábojútó ilẹ̀ náà, sọ̀rọ̀ líle sí wa, ó sì fi ẹ̀sùn kàn wá pé a wá yọ́ ilẹ̀ náà wò ni.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 42

Wo Jẹ́nẹ́sísì 42:30 ni o tọ