Jẹ́nẹ́sísì 42:4 BMY

4 Ṣùgbọ́n Jákọ́bù kò rán Bẹ́ńjámínì àbúrò Jósẹ́fù lọ pẹ̀lú wọn nítorí ẹ̀rù ń bàá kí aburú má ba à ṣẹlẹ̀ síi.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 42

Wo Jẹ́nẹ́sísì 42:4 ni o tọ