Jẹ́nẹ́sísì 43:11 BMY

11 Nígbà náà ni Ísírẹ́lì baba wọn wí fún wọn, “Bí ó bá rí bẹ́ẹ̀, èyí ni kí ẹ ṣe: Ẹ mú àwọn ohun dáradára ilẹ̀ yìí lọ́wọ́ lọ bí ẹ̀bùn fún ọkùnrin náà-ìpara díẹ̀, oyin díẹ̀, tùràrí àti òjíá, èso Písítakíò àti eso álímíndì

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 43

Wo Jẹ́nẹ́sísì 43:11 ni o tọ