Jẹ́nẹ́sísì 43:21 BMY

21 Ṣùgbọ́n níbi tí a ti dúró ní ọ̀nà láti sùn ní alẹ́, nígbà tí a tú àpò oúnjẹ wa, ẹnìkọ̀ọ̀kan wa bá owó oúnjẹ tirẹ̀ tí ó rà lẹ́nu àpò láì lé, láì dín. Nítorí náà òun nìyí, a ti mu-un padà wá pẹ̀lú wa.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 43

Wo Jẹ́nẹ́sísì 43:21 ni o tọ