Jẹ́nẹ́sísì 43:33 BMY

33 A mú àwọn ọkùnrin náà jókòó lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, bí wọ́n ṣe dàgbà sí, láti orí ẹ̀gbọ́n pátapáta dé orí èyí tí ó kéré pátapáta, wọ́n sì ń wo ara wọn tìyanu tìyanu.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 43

Wo Jẹ́nẹ́sísì 43:33 ni o tọ