Jẹ́nẹ́sísì 44:17 BMY

17 Ṣùgbọ́n Jósẹ́fù dáhùn pé, “Ká má rí i pé mo ṣe irú nǹkan bẹ́ẹ̀! Ẹni tí a bá kọ́ọ̀bù mi lọ́wọ́ rẹ̀ nìkan ni yóò di ẹrú mi, ẹ̀yin tí ó kù, ẹ máa lọ sọ́dọ̀ baba yín ní àlàáfíà.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 44

Wo Jẹ́nẹ́sísì 44:17 ni o tọ