Jẹ́nẹ́sísì 44:20 BMY

20 A sì dáhùn pé, ‘A ni baba tí ó ti darúgbó, ọmọkùnrin kan sì wà pẹ̀lú tí a bí fún un ní ọjọ́ ogbó rẹ̀. Ẹ̀gbọ́n rẹ̀ ti kú, òun nìkan sì ni ó kù nínú àwọn ọmọ ìyá rẹ̀, baba rẹ̀ sì fẹ́ràn an rẹ̀.’

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 44

Wo Jẹ́nẹ́sísì 44:20 ni o tọ