Jẹ́nẹ́sísì 44:22 BMY

22 A sì sọ fún olúwa à mi pé, ‘Ọmọkùnrin náà kò le è fi baba rẹ̀ sílẹ̀, bí ó bá dán-an wò baba rẹ̀ yóò kú.’

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 44

Wo Jẹ́nẹ́sísì 44:22 ni o tọ