Jẹ́nẹ́sísì 44:28 BMY

28 Ọ̀kan nínú wọn lọ kúrò lọ́dọ̀ mi, mo sì wí pé, “Dájúdájú a ti fà á ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ.” N kò sì tí ì ri láti ọjọ́ náà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 44

Wo Jẹ́nẹ́sísì 44:28 ni o tọ