Jẹ́nẹ́sísì 44:34 BMY

34 Báwo ni mo ṣe lè padà tọ baba mi lọ láì bá ṣe pé ọmọ náà wà pẹ̀lú mi? Rárá, mi ò fẹ́ kí n rí ìbànújẹ́ tí yóò dé bá baba mi.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 44

Wo Jẹ́nẹ́sísì 44:34 ni o tọ