Jẹ́nẹ́sísì 44:8 BMY

8 A tilẹ̀ mú owó tí a rí lẹ́nu àpò wa padà tọ̀ ọ́ wá láti ilẹ̀ Kénánì. Nítorí náà èéṣe tí àwa yóò fi jí wúrà tàbí idẹ ní ilé olúwa à rẹ?

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 44

Wo Jẹ́nẹ́sísì 44:8 ni o tọ