Jẹ́nẹ́sísì 45:27 BMY

27 Ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n sọ ohun gbogbo tí Jósẹ́fù ti sọ fún wọn fún un tí ó sì rí kẹ̀kẹ́ ẹrù tí Jósẹ́fù fi ránṣẹ́ láti gbé e padà wá, iyè Jákọ́bù, baba wọn ṣọ.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 45

Wo Jẹ́nẹ́sísì 45:27 ni o tọ