1 Báyìí ni Ísírẹ́lì mú ìrìn-àjò rẹ̀ pọ̀n pẹ̀lú ohun gbogbo tí ó ní, nígbà tí ó sì dé Báá-Ṣébà, ó rúbọ sí Ọlọ́run Ísáákì baba rẹ̀.
Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 46
Wo Jẹ́nẹ́sísì 46:1 ni o tọ