Jẹ́nẹ́sísì 46:12 BMY

12 Àwọn ọmọkùnrin Júdà:Ẹ́rì, Ónánì, Ṣélà, Pérésì àti Ṣérà (ṣùgbọ́n Ẹ́rì àti Ónánì ti kú ní ilẹ̀ Kénánì).Àwọn ọmọ Pérésì:Ésírónì àti Ámúlù.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 46

Wo Jẹ́nẹ́sísì 46:12 ni o tọ