Jẹ́nẹ́sísì 46:6 BMY

6 Wọ́n tún kó àwọn ohun ọ̀sìn wọn àti gbogbo ohun-ìní tí wọ́n ti ní láti ilẹ̀ Kénánì, Jákọ́bù àti gbogbo irú-ọmọ rẹ̀ sọ̀kalẹ̀ lọ sí Éjíbítì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 46

Wo Jẹ́nẹ́sísì 46:6 ni o tọ