Jẹ́nẹ́sísì 47:1 BMY

1 Jósẹ́fù lọ sọ fún Fáráò pé, “Baba mi àti àwọn arákùnrin mi, pẹ̀lú agbo ẹran, agbo màlúù àti ohun gbogbo tí wọ́n ní, ti dé láti ilẹ̀ Kénánì, wọ́n sì ti wà ní ilẹ̀ Gósénì báyìí.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 47

Wo Jẹ́nẹ́sísì 47:1 ni o tọ