Jẹ́nẹ́sísì 47:13 BMY

13 Ṣùgbọ́n kò sí oúnjẹ ní gbogbo ilẹ̀ náà nítorí tí ìyàn náà mú púpọ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí ilẹ̀ Éjíbítì àti ilẹ̀ Kénánì gbẹ nítorí ìyàn náà.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 47

Wo Jẹ́nẹ́sísì 47:13 ni o tọ