Jẹ́nẹ́sísì 47:27 BMY

27 Àwọn ará Ísírẹ́lì sì tẹ̀dó sí Éjíbítì ní agbégbé Gósénì. Wọ́n ní ohun-ìní fún ara wọn, wọ́n sì bí sí i tó bẹ́ẹ̀ tí wọ́n pọ̀ si gidigidi ní iye.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 47

Wo Jẹ́nẹ́sísì 47:27 ni o tọ