Jẹ́nẹ́sísì 47:9 BMY

9 Jákọ́bù sì dá Fáráò lóhùn, “Ọdún ìrìn-àjò ayé mi jẹ́ àádóje (130), ọjọ́ mi kò pọ̀, ó sì kún fún wàhálà, ṣíbẹ̀ kò ì tí ì tó ti àwọn baba mi.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 47

Wo Jẹ́nẹ́sísì 47:9 ni o tọ