Jẹ́nẹ́sísì 48:15 BMY

15 Nígbà náà ni ó súre fún Jósẹ́fù wí pé,“Ǹjẹ́ kí Ọlọ́run, ẹni tí baba miÁbúráhámù àti Ísáákì rìn níwájú Rẹ̀,Ọlọ́run tí ó ti jẹ́ olùtọ́jú àti aláàbòmi ní gbogbo ọjọ́ ayé mi títí di òní,

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 48

Wo Jẹ́nẹ́sísì 48:15 ni o tọ