Jẹ́nẹ́sísì 48:20 BMY

20 Ó súre fún wọn lọ́jọ́ náà pé,“Ní orúkọ yín ni Ísírẹ́lì yóò máa súre yìí pé:‘Kí Ọlọ́run ṣe ọ́ bí i ti Éfúráímù àti Mánásè.’ ”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 48

Wo Jẹ́nẹ́sísì 48:20 ni o tọ