Jẹ́nẹ́sísì 49:13 BMY

13 “Ṣébúlúnì yóò máa gbé ní etí òkun,yóò sì jẹ́ èbúté fún ọkọ̀ ojú omi,agbégbé rẹ yóò tàn ká títí dé Ṣídónì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 49

Wo Jẹ́nẹ́sísì 49:13 ni o tọ