Jẹ́nẹ́sísì 49:26 BMY

26 ìbùkún baba rẹ pọ̀ púpọ̀ju ìbùkún àwọn òkè ńlá ìgbàanì,ju ẹ̀bùn ńlá àwọn òkè láéláé.Jẹ́ kí gbogbo èyí sọ̀kalẹ̀ sí orí Jóṣẹ́fù,lé ìpéǹpéjú ọmọ aládé láàrin arákùnrin rẹ̀.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 49

Wo Jẹ́nẹ́sísì 49:26 ni o tọ