Jẹ́nẹ́sísì 49:29 BMY

29 Nígbà náà ni ó fún wọn ní àwọn ìlànà yìí, “Ọjọ́ ikú mi kù fẹ́ẹ́fẹ́. Kí ẹ sin mí sí ibojì pẹ̀lú àwọn baba mi ní inú àpáta ní ilẹ̀ Hítì ará Éfúrónì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 49

Wo Jẹ́nẹ́sísì 49:29 ni o tọ