Jẹ́nẹ́sísì 5:3 BMY

3 Nígbà tí Ádámù di ẹni Àádóje ọdún (130), ó bí ọmọkùnrin kan tí ó jọ ọ́, tí ó jẹ́ àwòrán ara rẹ̀, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Ṣétì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 5

Wo Jẹ́nẹ́sísì 5:3 ni o tọ