Jẹ́nẹ́sísì 50:10 BMY

10 Nígbà tí wọ́n dé ilẹ̀ ìpakà Átadì, ní ẹ̀bá Jọ́dánì, wọn pohùn réré ẹkún; Níbẹ̀ ni Jósẹ́fù sì tún dúró ṣọ̀fọ̀ baba rẹ̀ fún ọjọ́ méje.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 50

Wo Jẹ́nẹ́sísì 50:10 ni o tọ