Jẹ́nẹ́sísì 50:2 BMY

2 Nígbà náà ni Jósẹ́fù pàṣẹ fún àwọn oníṣègùn tí ó wà ní ìkáwọ́ rẹ̀ pé kí wọn kí ó ṣe òkú Ísírẹ́lì baba rẹ̀ lọ́jọ̀, àwọn oníṣègùn náà sì ṣe bẹ́ẹ̀,

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 50

Wo Jẹ́nẹ́sísì 50:2 ni o tọ