Jẹ́nẹ́sísì 50:26 BMY

26 Báyìí ni Jóṣẹ́fù kú nígbà tí ó pé àádọ́fà (110) ọdún. Lẹ́yìn ìgbà tí wọ́n se òkú rẹ̀ lọ́jọ̀ tan, a gbé e sí inú pósí ní Éjíbítì.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 50

Wo Jẹ́nẹ́sísì 50:26 ni o tọ