Jẹ́nẹ́sísì 6:13 BMY

13 Ọlọ́run sì wí fún Nóà pé, “Èmi yóò pa gbogbo ènìyàn run, nítorí ilẹ̀ ayé kún fún ìwà ipá nípaṣẹ̀ wọn. Èmi yóò pa wọ́n run àti ayé pẹ̀lú.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 6

Wo Jẹ́nẹ́sísì 6:13 ni o tọ