Jẹ́nẹ́sísì 6:15 BMY

15 Báyìí ni ìwọ yóò ṣe kan ọkọ̀ náà: Gígùn rẹ̀ ní òòró yóò jẹ́ ọ̀ọ́dúnrún ìgbọ̀nwọ́, ìbú rẹ̀ yóò jẹ́ àádọ́ta ìgbọ̀nwọ́, nígbà tí gíga rẹ̀ yóò jẹ́ ọgbọ̀n ìgbọ̀nwọ́.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 6

Wo Jẹ́nẹ́sísì 6:15 ni o tọ