Jẹ́nẹ́sísì 6:17 BMY

17 Èmi yóò mú ìkún omi wá sí ayé láti pa gbogbo ohun ẹlẹ́mìí run, lábẹ́ ọ̀run. Gbogbo ẹ̀dá tí ó ní èémí ìyè ní inú. Gbogbo ohun tí ó wà nínú ayé yóò parun.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 6

Wo Jẹ́nẹ́sísì 6:17 ni o tọ