Jẹ́nẹ́sísì 6:7 BMY

7 Nítorí náà, Olúwa wí pé “Èmi yóò pa ènìyàn tí mo ti dá run kúrò lórí ilẹ̀, ènìyàn àti ẹranko, àti ohun tí ń rákò, àti ẹyẹ ojú ọ̀run, nítorí inú mi bàjẹ́ pé mo ti dá wọn.”

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 6

Wo Jẹ́nẹ́sísì 6:7 ni o tọ