Jẹ́nẹ́sísì 7:17 BMY

17 Òjò náà sì rọ̀ ní àrọ̀ìrọ̀dá fún ogójì ọ̀sán àti ogójì òru, ọkọ̀ náà sì ń léfòó lórí omi, kúrò lórí ilẹ̀ bí omi náà ti ń pọ̀ sí i.

Ka pipe ipin Jẹ́nẹ́sísì 7

Wo Jẹ́nẹ́sísì 7:17 ni o tọ